TANPAN Conference: Àwọn ilúmọ̀ọ́káá kalẹ̀ sí Ibadan

Awọn agba osere tiata

Oríṣun àwòrán, Realyomifabiyi

Àkọlé àwòrán, Mo le gbe ọ, O ju bayi lọ ni Yomi Fabiyi s fun Mide Martins
Madam Sajẹ. ati Ọdun Adekọla

Oríṣun àwòrán, odunomoadekola

Àkọlé àwòrán, Ọdunlade Adekọla ati Fausat Balogun ni wọn dijọ maa n kopa iya ati ọmọ ninu ọpọ ere tiata.
Taiwo Hazzan ta mọ si Ogogo ati Ọdunlade Adekọla

Oríṣun àwòrán, odunomoadekola

Àkọlé àwòrán, A ku ọdun , ẹmi wa yoo se pupọ ọdun laye ni Ogogo ati Ọdunlade n sọ fun ara wọn.
Ọdunlade Adekola

Oríṣun àwòrán, odunomoadekola

Àkọlé àwòrán, Mo tẹ ara mi lọrun pẹlu omi yii, ongbẹ ko dara lara ni Ọdunlade Adekọla n sọ.
Awọn gbajumọ osere tiata

Oríṣun àwòrán, odunomoadekola

Àkọlé àwòrán, "Ta lo dagba ju laarin wa, ẹ ba wa da si?" ni Mr Latin n beere.
Femi Adebayo, Tijani ati Odunlade Adekola

Oríṣun àwòrán, odunomoadekola

Àkọlé àwòrán, Ọsan to ri gbajumọ ti ko bọ ni awọn mẹẹtẹta yii, odu si ni wọn, wọn kii se aimọ fun oloko lagbo tiata.
Awọn agba osere tiata

Oríṣun àwòrán, odunomoadekola

Àkọlé àwòrán, Ọdunlade Adekọla ni jo ya, ijo ree, jẹ ka jo
Olaniyi Afonja ati Tijani

Oríṣun àwòrán, Sanyeri02

Àkọlé àwòrán, Sanyeri ni "Ọrẹ jọ mi, mo jọ ọrẹ mi."
Awọn gbajumọ osere tiata

Oríṣun àwòrán, Sanyeri02

Àkọlé àwòrán, Awa la wa ri ara wa, bi ologinni ti n ri ọmọ Ẹkun...
Ọdunlade gbe Sanyẹri soke.

Oríṣun àwòrán, Sanyeri02

Àkọlé àwòrán, Ọdunlade Adekọla ni melo ni gbogbo ara Sanyẹri, ti oun ko lee gbe soke.
Antar Laniyan ati Lere Paimọ

Oríṣun àwòrán, Antarthywill

Àkọlé àwòrán, Awa agba aja, ti kii ba awo jẹ naa peju sibi ipade Tanpan
Awọn gbajumọ osere tiata

Oríṣun àwòrán, Iteledicon01

Àkọlé àwòrán, Ọrẹ law n se, a ko ja rara ni awọn agba osere yii sọ
Awọn agba osere tiata

Oríṣun àwòrán, Realyomifabiyi

Àkọlé àwòrán, Gbogbo wa la peju
Ọdunlade Adekọla ati Mr Latin

Oríṣun àwòrán, odunomoadekola

Àkọlé àwòrán, Ẹrin keke lẹnu awọn osere tiata meji, Ọdunlade Adekọla ati Bọlaji Amusan, ta mọ si Mr Latin.