Èyí ni ìtàn bí ẹni tí mó gbọ́njú mọ̀ bíi bàbà ṣe fipá bá mi lájọṣepọ̀
Iriri arabinrin Fatima Ishiaku nipa ifipabanilopọ bẹrẹ lati igba to ti wa ni ọdun marun un. kii ṣe ara ita tabi aladugbo lo hu iwa buruku yii siii, bikoṣe ẹni ti o gbọnju mọ gẹgẹ bii baba rẹ.
Gẹgẹ bi Fatima ṣe sọ iṣẹlẹ fi ojojumọ ṣẹlẹ titi di igba to fi pe ọdun mẹrinla.
Nibayii, Fatima ti le ni ogoji ọdun ṣugbọn apa ohun toju rẹ ri yii ko tii fi i silẹ.
- Ìdí tí mi ò fi lègbà kí ẹnikẹ́ni fọwọ́ tẹ ara mi gẹ́gẹ́ bí olórin-Sola Allyson
- Pákó ni mò ń tà ní Bodija, ṣùgbọ́n ọmọ mí ní '1st class' - Aliyu
- Kò sẹ́ni tó wù láti jẹ́ àkàndá, ẹ má dẹ́yẹ sí wọn mọ́- Fola
- N kò mọ̀ pé ojú mi ṣì lè là mọ́ lọ́wọ́ ìgbájú- Boluwatifẹ FUTA
- Wòólì Ajayi kú ní ìlú Àgelú, òkú rẹ pòórá, ìjọ sin pósí lásán!
- Kìí ṣe gbogbo ohun tí dókìtà ni kí n má jẹ torí àìsàn jẹjẹrẹ ni mo tẹ̀lé- Soyinka
- Wo bí kòkòrò ààrùn HIV se bẹ̀rẹ̀ lágbàyé!
- A jọ ṣe ìyàwó pọ̀, a jọ bímọ ní ọjọ́ kan náà, a tún jọ máa ń ṣàìsàn pọ̀ ni