Lagos-Ibadan road: Ọkọ̀ agbépo tó gbiná ní Ibafo dá súnkẹrẹ fàkẹrẹ sílẹ̀
Ọkọ agbepo tun to gbina ni Ibafo loju popo ilu Eko si Ibadan ti da sunkẹrẹ fakẹrẹ ọkọ silẹ loju titi naa.
Iya di meji fawọn arinajo loju popo naa lẹyin ti ọna naa di, eleyi ti ọkọ ko le rin geere tẹlẹ nitori iṣẹ to n lọ lori titi naa.
Florence Okpe to jẹ alukoro fun ileeṣẹ ẹshọ oju popo nipinlẹ Ogun sọ fawọn onimọto pe ki wọn farabalẹ pe awọn ẹshọ oju popo yoo giyanju lati gbe ọkọ naa kuro loju ọna.
- Ìjọba Nàìjíríà ti ránsẹ pé àsoju ijọba ni South Africa láti dari wálé
- Ọlọ́pàá fi afẹ́fẹ́ tajú-tajú àti omi tú àwọn tó fẹ́ ṣun ilé ìtajà ShopRite l‘Abuja ká
- Èèmọ̀ rèé o! Tọkọtaya, ọmọ mẹ́ta àti àlejò kú sínú ilé l'Oshodi
- Iṣẹ́ ṣẹ̀ṣẹ̀ bọ́ lọ́wọ́ Seth Ator tó yìnbọn pa ọ̀pọ̀ èèyàn ní Texas ni- ọlọ́pàá
- Àwọn èèyàn Gómìnà Yahaya Bello ló da ìbò abẹ́nú PDP rú- Ọlọgbọndiyan
- Àjẹ́ àti Aṣẹ́wó ní ìyá Rainbow - Òjòpagogo