Wo àwọn àwòràn tó làmìlaaka nílẹ̀ Adúláwọ̀ lọ́sẹ̀ yìí

Oríṣun àwòrán, Reuters
Ẹgbẹlẹgbẹ awọn eniyan ni wọn wa ṣe idaro gbajugbaja olorin n ni DJ Arafat.
Abidjan ni orilẹ-ede Ivory Caost gablejo awọn ero nibi eto isinku ọmọ ódun mẹtalelọgbọn naa to ku nibi ijamba to ni lori alupupu rẹ.
Koda, aarẹ ilẹ Ivory Coast, Alassane Quattara ati Davido gan an wa ni papa iṣere Félix Houphouet Boigny Stadium ti wọn ti ṣe ẹyẹ ikẹyin fun Arafat.

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Oríṣun àwòrán, EPA

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Ni Joannesburg to jẹ olu ilu orilẹ-ede South Africa ni awọn alagbara ti n dan ara wo ti wọn n ja fawọn onworan paapaa awọn ololufẹ.

Oríṣun àwòrán, EPA
Lọjọru to kọja ni Iman ara Somalia to n rirnrin oge wọ aṣọ alarabra yii.
O wọọ nibi ajọdun fiimu agbaye to waye ni Vernice ni orilẹ-ede Italy.

Oríṣun àwòrán, AFP
Gbajugbaja oṣere, Candice Swanepoel to wa lati orilẹ-ede South Africa lo duro ya fọto ninu omi yii.

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Eyi ni ogbontarigi olorin takasufe ọmọ Naijiria, DBanj nigba to n ṣere ni ile iwe giga Brixton Academy ni London lọjọ Aiku.
O ti kọkọ sọ fun BBC pe laipẹ ni iyawo oun a to bimọ ikoko tuntunÀwọn olórin Nàìjíríà kẹ́dùn ikú ọmọ DBanj

Oríṣun àwòrán, AFP
Odun "Fatchue" ni ọdun ti awọn ọmọde fi n palẹmọ de ipo adari lọjọ iwaju.

Oríṣun àwòrán, AFP

Oríṣun àwòrán, EPA
Ni orilẹ-ede Kenya ni a ti ri awọn ọmọ ogun ilẹ yii ti wọn n ṣo diẹ lara awọn erinmi ni Kenya.
Won n pese aabo fun eranko yii bo ṣe n wa ibi to maa ye ẹyin si lọjọ Eti to kọja.
- Kíkọ́ ẹ̀kọ́ gboyè nínú iṣẹ́ ìṣègùn ìbílẹ̀ yóò pèsè ìtọ́jú tó péye fọ́mọ Nàìjíríà- Ẹgbẹ́ àwọn dókítà
- Wọ́n mú ọjọ́ ìgbẹ́jọ́ agbésúnmọ́mí 9/11 tó ṣẹlẹ̀ l'Amẹrika
- Ọwọ́ ọlọ́pàá ti tẹ ọkùnrin kan tó pa ọ̀rẹ́ rẹ̀ nítorí N40 ní Kano
- Ẹ yé gba owó orí níbi ìdána ìyàwó mọ́, sísọmọbìnrin s'óko ẹrú ni- Daddy Freeze



























