Nigeria Elections 2019: Èrò àwọn ọmọ Nàíjíríà se ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ lóri ètó àlùfáà tàbí ìmámù lásìkò ìbò

Àkọlé fídíò, 2019 Elections: Èrò àwọn ọmọ Nàíjíríà se ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ lóri ètó àlùfáà tàbí ìmámù lásìkò ìbò

Ọpọlọpọ awọn ọmọ Naijiria sọ wi pe, adari ile ijọsin tabi imaamu wọn ko le e sọ fun wọn, ẹni ti wọn yoo dibo fun nitori pe ẹtọ awọn ni lati dibo yan ẹni to wu awọn.

Amọ, awọn miran sọ wi pe, alufaa awọn mọ ẹni to daraju laarin awọn oludije, nitorina awọn le e tẹle imọran rẹ lasiko idibo.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: