BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Àwọn abala
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ọdún iléyá 2018: Àwòrán tó jẹ arimaleelọ ni Yidi
21 Ògún 2018
Òní ní ọdún Eid il Adha eleyi tí ọpọ èèyàn mọ sí ọdún iléyá.
Àkọlé àwòrán,
Jakejado agbàyè ni awọn Musulumi ti kirun lasiko ọdún
Àkọlé àwòrán,
Awọn ara Ijebu n se ajọyọ ọdun ileya ni Eid Prayer Arena, Igbeba - Ijebu-Ode
Àkọlé àwòrán,
Àwọn ọmọ ọlọdun ń yẹra wo l'Osogbo
Àkọlé àwòrán,
Lọjọ ọdún yí àwọn mùsùlùmí yóò ki Irun rakaah méjì leyin tí Imam yoo pa eran tirẹ.
Àkọlé àwòrán,
Ọdun Ileya yii dun ni Ijẹbu, ẹsin ni ọmọde yii fi n jaye.
Àkọlé àwòrán,
Leyin ti Imam ba pa eran tan ni awon janmọ to ku le pa ti wọn náà
Àkọlé àwòrán,
Ní àwọn Aaye ìkìrun ati ọkunrin ati obirin ló peju
Àkọlé àwòrán,
Ọdun ba wa ni aye ati ni alaafia, o ye ka jo, ka si tun yọ pẹlu.
Àkọlé àwòrán,
Awọn olorin ati oni ilu fi ilu se idaraya fun awọn eniyan lasiko ayeye ileya ti ọdun yii.
Àkọlé àwòrán,
Awọn agbagba ni ilu Ibadan naa o gbeyin nibi ọdun ileya ni yidi Agodi, ilu Ibadan.
Àkọlé àwòrán,
Ọ̀pọ awọn olutaja lasiko odun yii lo n pariwo ko sowo nita rara lọdun Ileya yii.
Àkọlé àwòrán,
Ẹ ri ẹgbẹ wa bi, o yẹ wa n ti wa
Oríṣun àwòrán,
@BashirAhmaad
Àkọlé àwòrán,
Eegun nla lo n kẹyin igbalẹ́, aarẹ Muhammadu Buhari naa du ẹran ọdun
Ìròyìn tó ṣe kókó
Mò ń wá ọkọ, mo ti ṣetán láti fàyè gba ìfẹ́ nínu ọkàn mi – Princess Damilola
wákàtí 4 sẹ́yìn
Àlàyé lórí ohun tó ṣẹlẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Edo tó sọ akẹ́kọ̀ọ́ àti èèyàn 52 dèrò ọgbà ẹ̀wọ̀n
wákàtí 8 sẹ́yìn
Kà nípa Yoweri Museveni, ààrẹ Uganda tọ fẹ́ lọ fún sáà kéje
13 Sẹ́rẹ́ 2026
Ìwádìí kíkún lóríi kókó ìròyìn
Ìjọba mi yóò rí i dájú pé irú ìkọlù yíì kò ṣẹlẹ̀ mọ́- Gómìnà Seyi Makinde
8 Sẹ́rẹ́ 2026
Kí làwọn àtúntò tí ìjọba Nàìjíríà mú bá ètò ìdánwò WAEC àti NECO láti dènà àwọn aṣemáṣe?
7 Sẹ́rẹ́ 2026
Àlàyé lórí òfin tuntun tí UK gbé kalẹ̀ lórí àwọn tó ń fi ọkọ̀ ojú omi káwọn àjèjì wọlé
7 Sẹ́rẹ́ 2026
Ta ni Ọ̀mọ̀wé Olugbemisola Odusote, Adarí Obìnrin àkọ́kọ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga àwọn Amòfin tí Tinubu ṣẹ̀ṣẹ̀ yàn sípò?
7 Sẹ́rẹ́ 2026
Àwọn orílẹ̀ èdè wo ni Trump tún ń fojúsùn lẹ́yìn Venezuela?
7 Sẹ́rẹ́ 2026
Kí nídìí tí ilé aṣòfin ìpínlẹ̀ Rivers fi bẹ̀rẹ̀ ìgbésẹ̀ láti yọ Gómìnà Fubara nípò?
8 Sẹ́rẹ́ 2026
Kóòtù pàṣẹ kí ìjọba àpapọ̀ gbésẹ̀ lé dúkìá ₦213.2bn tí wọ́n tọpinpin kan Abubakar Malami fún ìgbà díẹ̀ ná
8 Sẹ́rẹ́ 2026
'Ó le fún mi gan, kí Ọlọ́run ṣíjú àánú wo àwọn èèyàn mi'
8 Sẹ́rẹ́ 2026
Kí ni òfin tí Amẹ́ríkà ṣẹ̀ṣẹ̀ gbé kalẹ̀ fáwọn tó bá fẹ́ ṣe ìrìnàjò afẹ́ tàbí lọ ra ọjà níbẹ̀ láti Nàìjíríà?
7 Sẹ́rẹ́ 2026
Ìròyìn tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn jùlọ
1
Ohun tí a mọ̀ rèé nípa ìṣẹ̀lẹ̀ ọkùnrin tó 'gún ìyàwó rẹ̀ pa' tóun náà sì pa ara rẹ̀ l'Ogun
2
Mò ń wá ọkọ, mo ti ṣetán láti fàyè gba ìfẹ́ nínu ọkàn mi – Princess Damilola
3
Àlàyé lórí ohun tó ṣẹlẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Edo tó sọ akẹ́kọ̀ọ́ àti èèyàn 52 dèrò ọgbà ẹ̀wọ̀n
4
Tinubu, Obasanjo, Sanwo-Olu àtàwọn mí-ìn ń ṣèdárò Ọba Akran tó wàjà ní Badagry
5
Kà nípa Yoweri Museveni, ààrẹ Uganda tọ fẹ́ lọ fún sáà kéje
6
''Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ti wà lójúfò fáwọn agbébọn tó ṣèlérí láti ṣèkọlù sí Ikoyi-Ile l'Ogbomoso''
7
Gbas-gbos ní ìpínlẹ̀ Rivers àti àtunbọ̀tán òṣèlú bàbá ìsàlẹ̀ nínú òṣèlú Nàìjíríà
8
Kókó nǹkan méje tí Chimamanda ń béèrè lọ́wọ́ ilé ìwòsan Euracare lórí ikú ọmọ rẹ̀
9
Ìjọba ilẹ̀ òkèrè dá $9.5m tí àwọn kan jí kó lọ sílẹ̀ wọn padà fún Naijiria
10
Ìpínlẹ́ Katsina ṣàlàyé ìdí tó fi fẹ́ẹ́ tú agbésùnmọ̀mí 70 sílẹ̀
You might also like:
news
|
sport
|
weather
|
worklife
|
travel
|
future
|
culture
|
world
|
business
|
technology