Ẹ ká díẹ nínú ìmọràn tí ará ìlú Èkìtì n gba Fáyẹmí
Awọn èèyèn ìpílẹ̀ Èkìtì ti dibo yan Ọmọwe Kayode Fayemi gẹgẹ bí Gómìnà wọn túntún ṣugbọn wọn kò fẹ dá iṣẹ ìṣèjọba dá òun nìkan.
Lójú òpó ayélujára Facebook wa, a béèrè ohun ti ará ìlú fẹ kí ọmọwe Fayemi gbajumọ ni kété t'oba bẹrẹ ìṣèjọba.
Díẹ rèé lára ohun ti wọn sọ ni yii



Sugbon kii se gbogbo eeyan lo dunu si bi Kayode Fayemi ti se jawe olubori


Kayode Fayemi fun ara rẹ mọ pe ipenija ti o wa nilẹ kii se kekere.
Lọpọ aaye ti o ti n sọrọ leyin idibo,nise ni o tenu mo dida ogo ilẹ Ekiti pada.
Sugbọn awọn amoye ni ẹnu lasan ko le mu iyipada wa si ipinlẹ Ekiti bi kii se ki Fayemi de okun sokoto re ko le daada.
Alagemo rẹ bayi ti bimo silẹ,afaimojo di ọwọ Fayemi ati bi o ba ti se dari eto ipinle Ekiti.














