You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Kókó ìròyìn t'òní: Wàhálà ìdàmẹ́wàá, Fáyòṣe tako Ààrẹ Bùhárí
Eyi ni awọn akojọpọ iroyin ti toni.
Kí la tún gbọ́ nípa ìdámẹ́wàá?
Laipẹ́ yii, olusọ̀aguntan ijọ RCCG, Pasito Adeboye sọ ni gbangba fun awọn ọmọ ijọ rẹ̀ wipe, ẹni ti ko ba san idamẹwa ko ni lọ si ọ̀run.
Ẹ o ranti wipe, ọrọ ti nja rain rain tẹ́lẹ̀ lori pe Daddy Freeze fesi si ọ̀rọ̀ pasitọ̀ Adeboye lori sisan idamẹ́wa leyii ti Freeze fesi pe idamẹ́wo ko pọn dandan.
Fáyóṣé fèsì lórí bí Buhari se ńdá Gaddafi lẹ́bi wàhálà darandaran
Gómìnà Ayọ̀délé Fáyóṣe ti ìpínlẹ̀ Èkìtì ti sọ pé ìdójútì ńláǹlà ni Ààrẹ Mùhámádù Bùhárí ń fún orílẹ̀èdè Nàìjíríà pẹ̀lú bí ó ṣe lọ ń di ẹ̀bi gulegule àwọn darandaran lórílẹ̀èdè Nàìjíríà ru Ààrẹ Gaddafi ti ilẹ̀
Libya tó ti di olóògbé . E ka ekunrere re ni bii
Awọn nkan miran ti ẹ ni lati mọ loni
Gbọ iroyin iṣẹju kan BBC
Awọn Fidio wa fun toni
Brọdá Shaggi: Kékeré ni mo ti mọ̀ pé iṣẹ́ apanilẹ́ẹ̀rín l'ọ̀nà mi
Ẹ wo àwọn ọmọ tí bàbá wọn fi s'ílẹ̀ sálọ ní Ghana