Toyin Adegbola Asewo to re Mecca: Kìí ṣe ònítíátà nìkan ló ní ìṣòro kí ìgbéyàwó máa dàrú

Àkọlé fídíò, Àgbà òṣèrébìnrin, Toyin Adegbola, tí ọ̀pọ̀ mọ̀ sí Asewo to re Mecca,

Agbe oserebinrin, Toyin Adegbola, ti ọpọ mọ si Toyin asẹwo to re Mecca ti sọrọ lori bi awọn eeyan ṣe maa n ro pe awọn osṣre tiata nikan lo ni isoro ati ri ile ọkọ gbe ati iṣoro nini iyawo ni ile.

Adegbola, lasiko to n kopa ninu ifọrọwerọ pẹlu ileeṣẹ BBC News Yoruba ni pe ọrọ ri bi awọn se n wo ati ko ki se awọn osere tiata nikan lo ni isoro igbeyawo.

"O n sẹlẹ kaakri, ko si ibi ti ko ti le sẹlẹ.

"Nitori pe wọn n wo wa, gbogbo aye lo n gbọ wa lo fi dabi pe onitiata nikan lo ni isoro igbeyawo."

Adegbola ni oun ba awọn obinrin sọrọ lati ni ifọriti ninu igbeyawo wọn.

O wa bu ẹnu atélu bi iku iyawo se n tọwọ ọkọ se wọpọ lawujọ wa.

Ko si nnkan to buru pe kẹ kọ ara yin si lẹ

Toyin Adegbola ni pe ti ko ba ti si agbọye laarin tọkọtya ko si nnkan to buru ninu poe ki wọn kọ arawọn silẹ.

Ekunrere wa ninu fidio yii