Caleb Adeniyi cica toys: Kò wú mi pé kí àwọn ọmọ Yoruba gbàgbé ilé àti orísun wọn ni mo ṣe sẹ ohun ìṣeré Yorùbá yìí
Nítorí kò wú mi kí àwọn ọmọ Yoruba gbàgbé ilé àti orísun wọn ni mo ṣe ṣàgbékalẹ̀ CICA Toys Yoruba.
Caleb Adeniyi jẹ ọmọ Yoruba to fi oke okun ṣe ibujoko lati ọpọlọpọ ọdun sẹyin lo sọ idi pataki to fi bẹrẹ iṣẹ iwadii lori ki ọmọ le maa fi ohun iṣere Yoruba ṣere ki wọn ma baa gbagbe orisun wọn.
O mẹnuba ipa pataki ti Iya oun ko lati kọ oun ni ede Yoruba ni oke okun lati kekere titi di isinyi.

Caleb menuba pataki ki omo ni ami idanimọ ede rẹ nipa kikọ nipa ede Yoruba pẹlu irọrun lasiko to ba n ṣere.
O ni eyi ko ni jẹ ki ọmọde gbagbe ile rara.

- Kíní yóò ṣẹlẹ̀ sí owó 200, 500 àti1000 Naira àtijó tí CBN yóò fòfin dè?
- Aláàfin Adeyemi ló mú mi fẹ́ràn àṣà Yorùbá síi pẹ̀lú iṣẹ́ ìwádìí- Paula Gomez, Oyìnbó tó ń gbé àṣà Yoruba ga
- Lẹ́yìn ti mo parí WAEC ni 1999 ni ayé gba ẹsẹ̀ lọ́wọ́ mi pẹ̀lú àlá láti ṣojú Nàìjíríà ni eré sísa
- Ṣé lóòótọ́ ní Kayamata jẹ́ àdódùn àti òògùn ìbílẹ̀ tí wọn fi ń so ọkùnrin mọ́lẹ̀?
- Àsìkò wo ló yẹ kí obìnrin bẹ̀rẹ̀ ìbálòpọ̀ padà lẹ́yìn ìbìmọ láìséwu?
- Ikorodu Bois: Ko si ẹni ti a kò lè sín jẹ!
- 'Ẹ̀rú bà mí lọ́jọ́ tí mo wọ bọ́ọ̀sì dẹ́rẹ́bà ọlọ́wọ́ kan lọ Ilorin', ìrírí àwọn èrò ọkọ̀ rèé
