Motiriolaoluwa Emmanuel jẹ ọmọ arídunnú fún mi- Rotimi Emmanuel
Lati ọdun meji ni Motiriolaoluwa ti n lu ilu 'drumset' - Baba Motiriolaoluwa
Rotimi Emmanuel to jẹ baba Motirioluwa sọ pe inu oun maa n dun si ọmọ naa nitori pe ọmọ aridunnu ni.
- 'Òǹtàjà aṣọ ni mí tẹ́lẹ̀, ọ̀dá owó ló sọ mi di alábárù'
- Mo ti di 'Millionaire' kí n tó pé 18 rárá, ìdí iṣẹ́ arìnrìnoge ni mo ti di òṣèré- Omotola Jalade Ekeinde
- Bí 2023 ṣe wọlé dé wẹ́rẹ́, Alapinni Oosa wúre ọdún fún ọmọ Yorùbá
- Ẹ máa ṣe àmín bí Adewale Alebiosu, àgbà òṣèré tíátà, ṣe ń gbàdúrà ọdún túntún fún yín
- Àánú táwọn èèyàn yóò fi máa sọ wí pé ọ̀nà wo lo gbà ni yóò wọlé fún ọ ní ọdún 2023
- Ẹni bá láyà: Ṣé ìwọ mọ àmì Yorùbá dáadàa?

Gbogbo igba ni inu ọmọ naa maa n dun.
Baba rẹ sọ pe lati éni ọdun meji lo ti n lu ilu naa.
Bakan naa ni baba re sọ pe ohun ajogunba ni nitori pe gbogbo ẹbi rẹ lo mọ nipa ilu lilu.
- 'Oníṣègùn, alágbo, aláàfáà, aládurà, gbogbo èèyàn ló ń wá ra ìkòkò àmọ̀ wa'
- Iṣẹ́ 'lecturer' ló wù mí ṣùgbọ́n ìdí mọ́káníìkì tírélà ni orí gbé mi lọ- Asabi Siyanbola
- Òṣèrè tíátà Muideen Oladapo gbàràdá lórí ètò 'Ṣé o láyà?'
- Wo oríṣì mágùn mẹ́sàn-án tí wọ́n n lé sí ara obìnrin nílẹ̀ Yorùbá
- Bí 2023 ṣe wọlé dé wẹ́rẹ́, Alapinni Oosa wúre ọdún fún ọmọ Yorùbá
