World Water Week 2022" Sarr láti Senegal rèé tó n ta omi tó mọ́ lówó pọ́ọ̀kù kí àìsàn lè dínkù ní agbègbè rẹ̀
Wo bi obinrin yii ṣe n pese omi to mọ gaara fun awọn eniyan agbegbe rẹ ni Senegal.
Ayajọ ọsẹ omi ni agbaye ti ọdun 2022 lo jẹ ki BBC wa obinrin akọni kan kan ni orile-ede Senegal.
Arabinrin Sarr lo n ta omi to mọ gaara fun awọn eniyan agbegbe naa lowo ti ko ga ju ara lọ rara.
- Orúkọ Aisha Yesufu náà wọ inú BBC 100 Women tí a fi ń sọri àwọn obìnrin tó pegedé ní 2020
- 'Garri ṣíṣe kò rọrùn fún àwa obìnrin'
- Ẹ̀rọ Medic Mobile ti sọ ayé dẹ̀rọ̀ fáwọn òṣìṣẹ́ elétò ìlera
- Gbogbo ìbéèrè tóo ní lọ́kàn nípa dída omira obìnrin lásìkò ìbálòpọ̀, ìdáhùn rèé
- Ọlọ́paàá ní wọ́n ṣèèṣì yìnbọn pa ọmọ mi tó ń tọ́ ọmọ oṣù mẹ́rin lọ́wọ́ ni- Ìyá Kager
- Oríṣìí àrùn mẹ́jọ tó máa ń ṣáábà mú aláboyún rèé
- 'Bíbélì kò ní kí tọkọ taya lu ara wọn pa'
Sarr lo wa ojutuu su iṣoro airi omi gidi mu to n koju awon eeyan rẹ ni agbegbe Nguekhokh ni Senegal ki wọn fi le bọ lọwọ aisan ti airi omi gidi mu n ko ba wọn.
O salaye pe ọdun mẹwaa saaju igba naa ni oun ti n kọminu lori ọrọ omi mimu nibẹ.
Nito ri pe o jẹ obinrin ko sọ pe o ko le mu idagbasoke ba ilu tabi agbegbe rẹ.
Ajọ Bill ati Melinda Gates lo sagbeteru fidio naa.