Aláàfin Oyo, Ọba Adeyemi 51 years on throne: Aláàfin Oyo, Ọba Lamidi Olayiwola Adeyemi lll pé ọdún 51 lórí àpèrè

Alaafin Oyo

Gbogbo ètò ló ti tò tí ohun gbogbo sì ti wà sẹpẹ́ níbi gbọ̀ngán tí Aláàfin Oyo, Ọba Lamidi Olayiwola Adeyemi lll, ti ń ṣe ayẹyẹ ọdún mọ́kànléláàdọ́ta lórí àpèrè àwọn baba rẹ̀.

Ní ọdún 1971 ni Ọba Lamidi gba ọ̀pá àṣẹ gẹ́gẹ́ bí aláṣẹ ìkejì òrìṣà nílùú Oyo.

Báyìí ló ṣe ń lọ níbi ayẹyẹ náà:

Alaafin Oyo

Gbogbo ilu Oyo lo mi titi pẹlu oniruuru aworan ati ọrọ ayẹsi ti awọn eeyan n fi sita nitori Alaafin Oyo.

Ibi ayẹyẹ ọdún mọ́kànléláàdọ́ta Aláàfin Ọyọ lórí àpèrè
Àkọlé àwòrán, Ibi ayẹyẹ ọdún mọ́kànléláàdọ́ta Aláàfin Ọyọ lórí àpèrè
Alaafin Oyo
Àwọn olóyè àti àlejò
Àkọlé àwòrán, Àwọn olóyè àti àlejò

Aláàfin fúnra rẹ̀, Ọba Lamidi Olayiwola Adeyemi lll náà ti wà ní kàlẹ̀ níbi ayẹyẹ ọ̀hún.

Àwọn àlejò ń kí Aláàfin
Àkọlé àwòrán, Àwọn àlejò ń kí Aláàfin
Àwọn àlejò ń kí Aláàfin
Àkọlé àwòrán, Àwọn àlejò ń kí Aláàfin
Àkàrà òyìnbó
Àkọlé àwòrán, Àkàrà òyìnbó