Olubadan: Wo ohun tó ń ṣẹlẹ̀ báyìí ní ilé Oloye Lekan Balogun tí wọ́n n sọ pé oyè Olubadan kàn

Oloye Moshood Olalekan Balogun ni opo n so pe Oba Olubadan kan lasiko yii.

Lekan
Àkọlé àwòrán, Enu ọna ile Oloye Lekan Balogun ni Ibadan
Lekan
Àkọlé àwòrán, Iwaju ita ile Oloye Lekan Balogun ni agbegbe Alarere ni Iwo Road
Lekan
Àkọlé àwòrán, Awon agbofinro naa wa ni ilé Oloye Lekan Balogun tí wọ́n n sọ pé oyè Olubadan kàn
Lekan
Àkọlé àwòrán, Oke ile Oloye Lekan Balogun ni Ibadan
Lekan
Àkọlé àwòrán, Awọn Onilu ti n da awon eeyan laraya ni ile Oloye Lekan Balogun ni Ibadan
Lekan
Àkọlé àwòrán, Awọn eekan Ilu ti n wa si ile Oloye Lekan Balogun ni Ibadan
Lekan
Àkọlé àwòrán, Awọn eeyan ti n fẹsẹ rajo ni ile Oloye Lekan Balogun ni Ibadan
Lekan
Àkọlé àwòrán, Enu ona abawole si ilé Oloye Lekan Balogun tí wọ́n n sọ pé oyè Olubadan kàn
Lekan
Àkọlé àwòrán, Lọkọọkan ni awọn eeyan n de si ilé Oloye Lekan Balogun tí wọ́n n sọ pé oyè Olubadan kàn
Lekan
Àkọlé àwòrán, Awọn ọkọ bọginni ni ilé Oloye Lekan Balogun tí wọ́n n sọ pé oyè Olubadan kàn
Lekan
Àkọlé àwòrán, Ile Oloye Lekan Balogun tí wọ́n n sọ pé oyè Olubadan kàn ni adugbo Alarere ni Iwo Road ni ilu Ibadan
Lekan
Àkọlé àwòrán, ọkan ko jọkan eeyan lo ti n de si ilé Oloye Lekan Balogun tí wọ́n n sọ pé oyè Olubadan kàn
Lekan
Àkọlé àwòrán, Awon Onilu ti n da awọn eeyan lara ya nile Lekan Balogun ni Iwo Road