Toyin Aimakhu Abraham ló kéde lórí ayélujára láìpẹ yìí pé ikú ti mú ìyá òsèrébìnrin Nkechi Blessing lọ

Oríṣun àwòrán, toyin_abraham
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1
Iku doro!
Toyin Aimakhu Abraham ló kéde lórí ayélujára láìpẹ yìí pé ikú ti mú ìyá òsèrébìnrin Nkechi Blessing lọ
Skip Instagram post
Allow Instagram content?
Warning: Third party content may contain advertsThis article contains content provided by Instagram. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read Instagram cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of Instagram post
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Wo èèwọ̀ mẹ́wàá to fi lè bọ́ lọ́wọ́ ewu iná gáàsì
- El-Rufai fẹ́ kó jàndùkú wọ apá Gúúsù ló jẹ́ kó tako òfin ìdaranjẹ̀ nígboro - Akeredolu
- Ìjọba ẹ má wòran, àjà ilé Aṣòfin tó ń jò le wó lé wa lórí - Aṣòfin sọ̀rọ̀ ṣókè!
- Ondo School Without Chairs: Iléèwé kan rèé tí kò ní àga, tábìlì, olùkọ́ àti ohun èèlò ìkẹ́kọ̀ọ́
- Tá à bá ti ibodè tó wọ Naijiria, ìyà kò bá jẹ wá lásìkò Coronavirus - Buhari
- Ọ̀run yóò ya bọ́ tí ààrẹ kò bá wá láti ẹ̀kùn gúúsù Nàíjíríà - Joe Igbokwe
- Kí ló ń fa ikú ọ̀wọọ̀wọ́ lẹ́yìn Davido?
- Ààrẹ tẹ́lẹ̀, Goodluck Jonathan ti sọ̀rọ̀ sókè, Ó ní wàhálà Nàìjíríà fẹ̀rẹ̀ gbẹ̀mí ìyá òun
Loju opo instagram Toyin Abraham naa ni iya Ire ti ni ki gbogbo ololufe re ranti oserebinrin naa, ninu adura won.
O ni ki won gbadura fun omo oloogbe naa, Nkechi Blessing lasiko yii.








