Sunday Igboho rán ọ̀kan lára àwọn ìsọ̀ǹgbè rẹ̀ ní ìlú Benini sí gbogbo yín

Àkọlé fídíò, Mo fi sánmọ̀ àti ilẹ̀, Mecca àti Medina búra pé Sunday Igboho kò sí nínú ewu níbí - Èèyan Igboho ní Cotonou

Awọn ololufẹ Igboho ni Benin fi ọrọ ranṣẹ si Naijiria.

Àkọlé fídíò, Okunrounmu: Ijọba Buhari jẹ ijiya Ọlọrun fun Naijiria