Se lootọ ni pe eniyan le ko Coronavirus lara ẹni to ti kú?

Àkọlé fídíò, Se lootọ ni pe eniyan le ko Coronavirus lara ẹni to ti kú?

Láìpẹ́ yìí ti olórí òṣìṣẹ́ ilé iṣẹ́ ààrẹ Abba Kiyari kú lẹ́yìn to lùgbàdì ààrùn Corornavirus ni ariwo gab ori atẹjiṣẹ́ twitter kan pé, ki lo de ti ajọ to n gbogun ti ajakalẹ aarun lorilede Naijira fi yọnda okú rẹ láti sin.

Ọ̀rọ̀ yii dá awuyewuye to pọ̀ silẹ̀ to si mú oníruuru ìbèèrè wá.

Sùgbọ́n, títí di asiko yìí ko ti si ẹri to fidi rẹ mulẹ pé enikẹni ko aarun coronavirus láti ara ẹni toku.