Xenophobia: Awọn ọmọ Naijiria n sọ ohun tó kàn lẹ́yìn ìpadàbọ̀ wọn
Ijọba lo ku ti a n bẹ bayii- ọmọ Naijiria
Awọn ọmọ Naijiria ti wọn koju ikọlu sawọn ajoji to waye ni South Africa ti n pada sile lati alẹ ana.
BBC Yoruba ba ninu wọn sọrọ to mẹnuba ibẹru rẹ bayii to ti pada sile lati wa tun igbesi aye rẹ bẹrẹ lọtun.
- Ìdí rè é tí mo ṣe lọ sí South Africa fún àpérò ọrọ̀ ajé - Ezekwesili ṣàlàyé
- Àwọn ọmọ Nàìjíríà 320 yóò padà wálé láti South Africa lọ́jọ́rú - Adama
- Àwọn ọmọ Naijiria sọ̀rọ̀ lórí ìgbẹ́jọ́ tó da ẹjọ́ Atiku nù!
- Àwọn ọmọ Naijiria ti ń wọ bàálù láti South Africa báyìí
- Àbábọ̀ mi sí orílẹ̀èdè South Africa rè é - Aṣojú Buhari
- Ajé ò! Ẹ wo fídíò òfò àti àdánù tó wáyé níbi ìkọlù sáwọn àjèjì ní South Africa
- Àwọn èèyàn to n fẹ̀hónú hàn dáná ṣun iléeṣẹ́ MTN n‘Ibadan