Ọ̀wọ́ngógó epo bẹntirò: NNPC ni 'ìròyìn ẹlẹ́jẹ̀' ni

LAGOS
Àkọlé àwòrán, Awọn eniyan yii n gba ọna ẹburu ta epo ni ilu Eko

Ile isẹ to n pese epo bẹntiro lorilẹ-ede Naijiria, NNPC ti kesi awọn ọmọ Naijiria pe iroyin ẹlẹjẹ ni ọwọngogo epo lorilẹ-ede Naijiria.

Adari ẹka to n risi ọrọ to jẹ mọ ara ilu ni ile iṣẹ NNPC, Ndu Ughamadu lo sọ pe irọ lasan ni awọn eniyan n pa ati wi pe ko si owongogo epo.

Àkọlé fídíò, Ọ̀dọ́kùnrin tó kọ́kọ́ ṣe ẹ̀rọ tó ń tu ìyẹ́ lára adìyẹ
Fuel Nussle

Oríṣun àwòrán, Other

Àkọlé àwòrán, Ọ̀wọ́ngógó epo bẹntirò: NNPC ni ìròyìn ẹẹ́jẹ̀' ni
Àkọlé fídíò, JAMB 2019: A ó fagi lé ìdànwò ẹni tó bá ṣe aṣemáṣe

Ugbamadu ni awọn ṣì ni àgbá epo tó lé ni biliọnu lítà kan nílẹ̀ fún lílò àwọn ènìyàn Naijiria.

Lagos
Àkọlé àwòrán, Awọn eniyan to lati ra epo ni awọn ilu nla nla ni Naijiria

Amọ ọpọlọpọ ara ilu ni Eko, Ondo, Abuja ati bẹẹ bẹẹ lo lo koju owongogo epo bẹntiro, ti o si fa sunkẹrẹ fakẹrẹ ọkọ lawọn ile epo kaakiri.

Àkọlé fídíò, Bí o ṣe lè fí òǹkà, ọ̀mọ̀ ìka tàbí ìkúùkù wọn oúnjẹ́