2019 Elections: Bí ìbò rírà ṣe ṣákóbá fún iṣẹ́ ìwé títẹ̀ ní Nàìjíríà
Àwọn òǹtẹ̀wé fi ẹ̀hónú hàn sí bí àwọn olóṣèlú ṣe ń kó owó tó yẹ kí wọ́n wá fi tẹ ìwé ìpolongo ìbò lọ́dọ̀ wọn pamọ́ láti máa fún àwọn ènìyàn kí wọ́n lè ta ìbò wọn.
Tẹ́lẹ̀ àwọn òntẹ̀wé ní àwọn máa ń rí jà dáadáa ṣùgbọ́n ohun gbogbo ti yí padà báyìí.