Nigeria Police: Eko, Oyo, Kwara, Anambra gba Ọ̀gá Ọ̀lọ́pàá tuntun

Oga Olopaa

Oríṣun àwòrán, @PoliceNG

Àkọlé àwòrán, Oga Olopaa

Adele ọga agba awọn ọlọpaa Naijiria, Mohammed Adamu ti kede orukọ awọn lọga lọga ni iṣẹ ọlọpaa to yan sipo.

Iyansipo naa ni o kan awọn lọga lọga to le ni aadọta to fi mọ ipo igbakeji ọga agba ọlọpaa ati awọn kọmisana ọlọpaa.

Lara awọn ipinlẹ Nigeria to gba kọmisana tuntun ni Eko, Ọyọ, Kwara ati Anambra.

Eyi jẹ jade ninu ikede ti agbẹnusọ fun ajọ ọlọpaa, Frank Mba fi sita.

Lara wọn niyii to kan ọmọ Yoruba yala nipa ipinlẹ ti wọn n ṣoju tabi pe wọn jẹ ọmọ Yoruba:

iii. AIG Adeyemi O. Ogunjemilusi, mni - Directing Staff NIPPS

xii. AIG Adeleye Olusola Oyebade, mni - AIG Zone 11, Osogbo

xv. AIG Folawiyo David, mni - AIG Training & Development

xix. CP Mu'azu Zubairu - CP Lagos State Command

xx. CP Ahmed Iliyasu - CP Ogun State Command

xxv. CP Asuquo Amba - CP Ekiti Command

xxvi. CP Abiodun Ige - CP Osun Command

xxx. CP Omololu Bishi - CP Benue Command

xxxi. CP Bola Longe - CP Nasarawa Command

xxxii. CP Isaac Akinmoyede - CP Plateau Command

xxxiv. CP Adeleke Yinka - CP Delta Command

xxxvi. CP Awosola Awotunde - CP Ebonyi Command

xli. CP Akeem Busari - CP Kogi Command

xlix. CP Undie Andie - CP Ondo Command

l. CP Olukolu Sina - CP Oyo Command

liv. Ag. CP Egbetokun Kayode - CP Kwara Command

lv. Ag. CP Odumosu Akeem - CP Edo Command