Ahmed Musa padanu ìyá rẹ̀ lẹyin aisan ranpẹ

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Agbabọọlu ọmọ Naijiria Ahmed Musa ti padanu iya rẹ bayi.

O fi iroyin naa to awọn ọmọ Naijiria leti lori Twitter ni Ọjọbọ niga to ni "Ọjọ ibanuje ni ọjọ yii jẹ fun aye mi. Mo ti padanu iya mi."

O ti sọ tẹlẹ pe iya oun ṣaarẹ ko to di pe o ku.

Ni ana ni o fi aworan iya rẹ sori Twitter ninu eyi to fi n ki pe ki o dara le.

Àwọn ìròyìn mìíràn tí ẹ lè nífẹ̀ẹ́ sí: