APC Primaries: ẹgbẹ́ òṣèlú kéde olùdíje 24 fún ipò gómìnà

Oríṣun àwòrán, Babajide Sanwoolu/Facebook
Lẹyin idibo abẹle ti ẹgbẹ oṣelu APC ṣe fun awọn oludije fun ipo gomina kaakiri orilẹede Naijiria, igbimọ amuṣẹya ẹgbẹ naa ti f'orukọ awọn mẹrinlelogun to jawe olubori lede.
1. Babajide Sanwo-Olu ni yoo dupo gomina ni Ìpinlẹ Eko labẹ asia ẹgbẹ APC lẹyin to pegede ninu ibo abẹle ti wọn ṣe.
Babajide Sanwo-Olu tó jẹ́ ẹni tó fi ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìbò ju gómìnà Akinwumi Ambode lọ nínú ìdìbò abẹ́lé ẹgbẹ́ òṣèlú APC l'Eko ti fi lmi ìmoore hàn.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
Wọnyi ni orukọ awọn oludije fun ipo gomina lawọn ipinlẹ mẹtalelogun yoku.
2. Ipinlẹ Yobe, Mai Mala Buni lo jawe olubori ninu idibo abẹle ti wọn.
3.Ipinlẹ Nasarawa- Abubakar A. Sule A.
4. Ipinlẹ Benue- Emmanuel Jimme
5. Ipinlẹ Rivers- Tonye Cole
6. Ipinlẹ Abia- Uche Ogah
7. Ipinlẹ Akwa Ibom- Nsima Ekere
8. Ipinlẹ Oyo- Adebayo Adelabu
9.Ipinlẹ Ogun- Dapo Abiodun
10.Ipinlẹ Delta- Great Ogboru
11.Ipinlẹ Cross River-Owan Enoh
12. Ipinlẹ Gombe- Inuwa Yahaya
13.Ipinlẹ Ebonyi- Sunny Ogboji
14. Ipinlẹ Taraba- Sani Abubakar Danladi
15. Ipinlẹ Kano- Abdullahi Umar Ganduje
16. Ipinlẹ Bauchi- Mohammed Abubakar
17. Ipinlẹ Plateau- Sim,on Lalong
18. Ipinlẹ Kaduna- Nasir El-Rufai
19. Ipinlẹ Jigawa- Mohammed Badaru Abubakar
20. Ipinlẹ Sokoto- Ahmed Aliyu
21. Ipinlẹ Kebbi- Abubakar Atiku Bagudu
22. Ipinlẹ Katsina- Aminu Bello Masari
23. Ipinlẹ Niger- Abubakar Sani Bello
24. Ipinlẹ Bornu- Babagana Umara-Zulum
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:












