Leah Sharibu ti lo irínwó ọjọ́ ní àhámọ́ Boko Haram

Akara oyinbo fun ọjọ ibi Leah Sharibu

Oríṣun àwòrán, Google, BBC

Àkọlé àwòrán, Akara oyinbo fun ọjọ ibi Leah Sharibu
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Leah Sharibu ti awọn agbesunmọmi Boko Haram jigbe ni ọdun to kọja, ti pe ọmọ ọdun mẹrindinlogun ni panpẹ wọn.

Leah Sharibu wa lara awọn ọmọbinrin ile iwe Dapchi ti ikọ agbesunmọmi Boko Haram jigbe ni Osu Keji, ọdun 2018, amọ ti wọn ko lati fi silẹ nitori o kọ lati kọ ẹsin kristẹni silẹ.

Àkọlé fídíò, Boko Haram yóò dá Leah sílé

Gẹgẹ bi ẹni se jẹ ọjọ ibi rẹ, awọn eniyan pejọ si ile ijọsin lati se ẹsin ọjọ ibi fun ọmọ naa to duro sinsin lori igbagbọ rẹ.

Lori ọju ẹrọ ibaraẹnisọrọ Twitter ni awọn eniyan ti ki Leah ku ọjọ ibi rẹ.

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

Skip X post, 2

End of X post, 2

Leah Sharibu
Àkọlé àwòrán, Leah Sharibu wa lara awọn ọmọbinrin ile iwe Dapchi ti ikọ agbesunmọmi Boko Haram jigbe ni Osu Keji, ọdun 2018.
Skip X post, 3
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 3

Bakan naa ni ọgọọrọ eniyan ni ilu Abuja parapọ lati se ifẹhọnu han pe ki ijọba orilẹede Naijiria ri wi pe wọn gba itusilẹ Leah Sharibu ni kiakia.

Àwọn ìròyìn míì tí ẹ lè nífẹ sí

Àkọlé fídíò, 'Bí ìrẹsì tèmi Ayinde bá ń pàkùta, kò tọ́ sẹ́nu aláàrù Barrymaade'