Diego Maradona lọ̀! Ẹ jẹ́ ká gbafẹ́ pẹ̀lú àwọn àwòdamiẹnu àwòrán nípa ìgbé ayé rẹ
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Àkọlé àwòrán, Diego Maradona gbe ife ẹyẹ lọwọ ni 1986, o tun se igbaradi, oun ati iyawo rẹ tẹlẹ ri Claudia ati awọn ọmọbinrin rẹ Dalma ati Gianina
Ka fi ẹgan si koda ka tun yọ kuro, agbabọọlu Maradona sọwọn lagbo ere bọọlu lagbaye.
Nigba to wa laye, orisi aworan lo safihan igbe aye gbajugbaja agbabọọlu to tun pada ṣe akọnimọọgba fun Lionel Messi.
Bo ṣe ka sọ nipa itu to pa lorileede rẹ ni Argentina ni , tabi bo ti ṣe ko ipa ribiribi biwọn ti ṣe gba ife ẹyẹ agbaye, igbe aye Maradona kun fun manigbagbe itan.
Diẹ ree ninu aworan igbe aye rẹ:
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Àkọlé àwòrán, Lọdun 1982 ni Maradopna ti kọkọ kopa ninu idije ife ẹyẹ agbaye ni Spain ṣugbọn lọdun 1986 niiraw rẹ tan ni Mexico...
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Àkọlé àwòrán, Maradona ba ọwọ pẹlu aṣọle ilẹ Gẹẹsi Peter Shilton ni abala to kangun si aṣekagba idije ife ẹyẹ agbaye lọdun 1986
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Àkọlé àwòrán, Goolu ti Mardona fọwọ jẹ ati eleyi to lamilaka to fi de a'\seyọri Argentina lori England
Oríṣun àwòrán, Rex Features
Àkọlé àwòrán, Maradona lagbabọọlu ti o pegede julọ nidije agbaye ọdun 1986
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Àkọlé àwòrán, Mardona gba ife Uefa Cup lọdun 1989 ati ife liigi meji ni Napoli. Ko si ẹni to wọ jẹsi rẹ nọmba 10 lati igba naa
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Àkọlé àwòrán, Ipenija lilo oogun oloro jẹ iṣoro kan to ba Maradona finra to si mu ki o maa tobi
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Àkọlé àwòrán, Maradona ati Messi lasiko to n ṣe akọnimọọgba Argentina
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Àkọlé àwòrán, Mraadona di aṣọ ti wọn ya aworan rẹ si lasiko ti Argentina n koju Naijiria