Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Awuyewuye lẹgbẹ oṣelu Labour Party
Bi igun igbimọ alaṣẹ ti Julius Abure n dari ṣe ni ki gomina ipinlẹ Abia atawọn marun-un mii
Lọ rọkun nile fungba kan na Fẹsun ṣeyi-ṣọhun lodi sofin ẹgbẹ
Amọ igun ti Nenadi Usman n dari ti fesi
Ki lo sọ?
Kan soju opo bbc yoruba
xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx
Ẹ dakun, ẹ gba wa, a o lowo mii mọ
Awọn mọlẹbi eeyan meje tawọn ajinigbe jigbe ni ipinlẹ Kwara lo rawọ ẹbẹ bẹẹ
Lẹyin ti wọn san miliọnu mẹrinla naira gẹgẹ bii owo itusilẹ
Ṣugbọn tawọn ajinigbe naa kọ lati tu awọn eeyan wọn silẹ ti wọn si n beere fun miliọnu mẹwaa mii
Wọn odidi apo irẹsi, adiyẹ mejila, kaadi lawọn ajinigbe naa tun gba
xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx
Eto yiyan poopu tuntun n tẹsiwaju lonii
Lẹyin tawọn cardinal ko fẹnuko lori ẹnikan lọjọru
Aago mẹwaa abọ owurọ yii leto idibo mii tun ti gberasọ
Ọpọ ero ti tun ti pe biba si St Peters square lati wo eefi ti yoo ru jade lati Vatican lonii
Ki ni ti eefi ninu yiyan poopu?
Fun ẹkunrẹrẹ
