Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Ẹ̀yin ọmọdé, ẹnikẹ́ni tó bá tẹ ẹ̀tọ́ yín mọ́lẹ̀ tábí ṣe aburú fún yin, ẹ sọ̀rọ̀ sókè, á o gbọ́ igbe yín
Aarẹ Bola Tinubu lo ṣeleri yii lasiko to darapọ mawọn ewe lati ṣayajọ awọn ọmọde tọdun yii
Tinubu ni ijọba oun yoo saa gbogbo ipa rẹ lati da bobo ẹtọ awọn ọmọde ni Naijira
ẹkunrẹrẹ wa lori BBC.Com/Yoruba
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Kí ló fa rògbòdìyàn níluu Omu Aran láàrin ọlọ́pàá, afurasí ọmọ Yahoo àti àwọn ọ̀dọ́, tàwọn obìnrin fi n ṣewọde?
BBC Yoruba ṣabẹwo si agbegbe ti ifẹhonuhan naa ti waye
lati beere ohun to ṣokunfa iwọde ọhun
Lọ soju opo wa fun alaye kikun lori iṣẹlẹ naa
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Àwọn olólùfẹ́ ẹgbẹ́ àgbábọ́ọ̀lù Liverpool tó ń ṣàjọyọ̀ gbígba ife ẹ̀yẹ Premier League ṣàgbákò ìjàmbá nibi ti wọn ti n yọ, àádọ́ta eeyan farapa
Ki lẹ ṣẹlẹ gan an?
awakọ kan ma lo ṣadeede ya wọ aarin awọn eeyan naa
Haa!
ẹwẹ, awọn ọlọpaa ti mu ọkunrin ọmọ ilẹ Gẹẹsi kan ti wọn sọ pe oun lo wa ọkọ naa
















