Ọ̀pọ̀ ohun aṣalóge olófùndídùn ló ń fàwọn ọmọdé ṣiṣẹ́ àìtọ́ - ìwádìí BBC tú àṣírí

Àkọlé fídíò, Ọ̀pọ̀ ohun aṣalóge olófùndídùn ló ń fàwọn ọmọdé ṣiṣẹ́ àìtọ́ - ìwádìí BBC tú àṣírí
Ọ̀pọ̀ ohun aṣalóge olófùndídùn ló ń fàwọn ọmọdé ṣiṣẹ́ àìtọ́ - ìwádìí BBC tú àṣírí

Awọn ọmọde lo n ṣa awọn eroja ti awọn alagbata ileeṣẹ aṣaraloge nlanla meji kan n lo lati ta fun wọn fi ṣe ọja wọn.

Iwadii BBC lori awọn ilana ti awọn ileeṣẹ kan fi n ṣe awọn eroja aṣaraloge olorundidun ti wọn n ta fihan pe awọn ọmọde ni wọn fi n ṣe iṣẹ ẹru lati ṣa eroja Jasmine ti awọn alagbata Lancome ati Aerin Beauty nlo ko fun awọn ileeṣẹ ti wn n ba ṣiṣẹ.

Gbogbo awọn ileeṣẹ to n ṣe awọn eroja aṣaraloge olorundidun ni wọn maa n sọ pe awọn ko fi aye gba lilo awọn ọmọ fi ṣiṣẹ lọna ti ko bofinmu.

L’Oréal, to ni awọn aṣaraloge olorundidun Lancome ni awọn ko fi ọrọ ẹtọ ọmọniyan ṣere rara. Estée Lauder to ni awọn eroja aṣaraloge olorundidun Aerin Beauty ni awọn ti kan si awọn alagbata awọn.