Kò ṣe é mà gbọ̀ ọ́
Orogun owo bẹrẹ lori adinku owo epo bẹntiroolu laarin ileeṣẹ ifọporọbi NNPC ati Dangote
Ṣe wọn tun ti kede adinku mii ni?
Bẹẹ ni o, NNPC naa ti kede adinku owo epo bẹntiroolu lawọn ile epo wọn
Laipẹ yii ni Dangote kede adinku iye to n gbepo fawọn alagbata eyi to jẹ ki araalu maa repo ra lẹdinwo.
Ẹkunrẹrẹ wa lori ikanni BBC Yoruba
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Olubadan o ku o, koko lara baba le bi ọta
ijọba ipinlẹ Oyo ti sọ pe irọ nla niroyin kan to jade lalẹ ana ọjọ Aje pe, Olubadan tilẹ Ibadan Ọba Owolabi Olakulehin ti waja
Kinni aafin Olubadan wa sọ nipa iroyin mii to ni wọn ti gbe Kabyesi kuro n'Ibadan lọ ilu miran fun itọju?
Kan soju opo BBC.Com/Yoruba ti o ba fẹ mọ
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Ọna ọfun ọna ọrun
Bẹẹ ni o
Eeyan meje ni wọn ti tẹ pa lasiko ti wọn n gba nnkan aawẹ
O ma ṣe o
Koda, Ọpọ eeyan lo farapa nibi iṣẹlẹ naa
Nibo lo ti ṣẹlẹ gan an?
Fun ẹkunrẹrẹ iroyin yii… ẹ kan si wa lori BBC Yoruba


