Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

A o gba rara, iru idajọ wo niyẹn?

Ta lo da ẹ lẹjọ to n dasọ bayii?

Ijọba ipinlẹ Eko ma lo morile ile ẹjọ to ga julọ ni Naijiria pe awọn ko faramọ idajọ ile ẹjọ kotẹmilọrun lori ọrọ dokita Femi Olaleye

Taa lo n jẹ bẹẹ?

O o ranti dokita ti ile ẹjọ ju sẹwọn gbere ni 2023, lori ẹsun pe o fi ipa ba ibatan iyawo rẹ to jẹ ọmọde lopọ

Ha, ha! Mo ranti. Ṣebi ile ẹjọ Kotẹmilọrun ti ni ko maa lọ sile layọ ati alafia

Bẹẹni! Idajọ yii gan ni ijọba Eko ni to tẹ awọn lọrun rara.

Oba Adesuyi Haastrup ti gbọpa aṣẹ gẹgẹ bi Owa Obokun tuntun fun ilẹ Ijesha

Lọjọ Aiku ni Gomina ipinlẹ Osun, Ademola Adeleke gbe ọpa aṣẹ naa le lọwọ niluu Ilesa

Atẹjade lati aafin Owa Obokun ni Ọba Haastrup ti wọ ipebi bayii ati pe

Ati pe ki ni?

Kan si oju opo bbc.com lati ka ẹkunrẹrẹ

O di gbere, o tun darinako

Aarẹ tẹlẹ ri ni Amẹrika tẹlẹ, Jimmy Carter ti ku lẹni ọgọrun-un ọdun

Oun ni aarẹ akọkọ ni Amẹrika ti yoo pe ọgọrun-un ọdun loke eepẹ