Kò ṣeé má gbọ̀ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Ko ṣee ma gbọọ
Kò ṣeé má gbọ̀ọ́

Ọkọ mi ko ji owo Naijiria pamọ soke okun

Maryam, iyawo aarẹ Naijiria tẹlẹ, Oloogbe Sani Abacha lo sọ bẹẹ

Iyawo Abacha ni Oloogbe tọju owo fun Naijiria ni, ki i ṣe ole

Ki wa lofin sọ nipa olori orilẹede to kowo pamọ lai jẹ ki araalu mọ.

BBC ba Ọmọwe Festus Adedayo, onimo oṣelu sọrọ lori eyi.

Ka alaye rẹ lori lohun ti ofin sọ ni BBC. COM/ Yoruba

…………………………………………………

Ajọ United Nations Population Fund, ti fidi ẹ mulẹ pe ọpọ eeyan ni ko fẹẹ bi ju ọmọ meji lọ mọ bayii.

Adari ajọ naa, Natalia Kanem, sọ pe kaakiri agbaye lawọn eeyan ti n din iye ọmọ ti wọn n bi ku.

Iwadii waye lawọn ilẹ okeere ati Naijiria, wọn ni ọrọ aje to dojuru wa lara idi to fi ri bẹẹ.

Ka iyoku loju opo wa.

,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,

Bàbá ẹni odun mejidinlaadọrin torí fóònù kó sí kaǹga n'Ibadan

Ileeṣẹ panapana ipinlẹ Oyo, sọ pe bawọn ko ba tete debẹ ni, ọrọ ko ba bẹyin yọ.

Nibo lo wa de duro bayii?