Kò ṣeé má gbọ̀ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Akojọpọ iroyin kaakiri agbaye
Kò ṣeé má gbọ̀ọ́

Ẹrin wo

Ayo Adebanjo, agba oṣelu ati olori igun Afenifere ti ku o

Jare Ajayi, ọmọ ẹgbẹ Afẹnifẹre fidi ẹ mulẹ fun BBC

Pe Adebanjo dagbere faye loni ọjọ Ẹti

Ẹni ọdun mẹrindinlọgọrun-un ni baba Adebanjo ko too dagbere faye

Bawo waa ni eto isinku?

Alaye kikun wa loju opo wa

................................................................................

Aba iṣuna 2025 yii le ma ri bi araalu ṣe n reti

Iyẹn aba ti wọn buwọlu lana ode yii

Bẹẹ ni, awọn awoye lẹka ọrọ aje sọ pe owo to n bẹ nilẹ lo dun na

Wọn ni ẹyawo ati ai le pese nnkan funra wa yoo ṣakoba fun aba naa

Iyẹn le diẹ o

...............................................................

Ọtọ lodo aro, ọtọ lodo ẹjẹ

A o ni i pade eyikeyi ninu wọn o.

Odo kan ti parada d'ẹjẹ lArgentina

Araalu sọ pe awọn kan lo n dana sun ilẹ nidaji ọjọ naa

Bawo niyẹn ṣe wa sọ odo di ẹjẹ?