Wo bí àìsàn ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn ṣe ń bá èèyàn bíi mílíọ̀nù kan àtààbọ̀ tó tó ọmọ ogójì ọdún fínra

Àkọlé fídíò, Wo bí àìsàn ìrẹ̀sì ọkàn ṣe ń bá èèyàn bíi mílíọ̀nù kan àtààbọ̀ tó tó ọmọ ogójì ọdún fínra
Wo bí àìsàn ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn ṣe ń bá èèyàn bíi mílíọ̀nù kan àtààbọ̀ tó tó ọmọ ogójì ọdún fínra

Awọn onimọ iṣegun ti fidi rẹ mulẹ pe ọpọ eeyan to wa laye lo ni aisan irẹwẹsi ọkan ti wọn ko tẹ mọ rara.

Bakan naa ni awọn miran mọ, ṣugbọn ti wọn ko ri itọju to peye.

O to miliọnu kan ataabọ eeyan to ti pe ẹni ogoji ọdun lorilẹede South Korea to ni irẹsi ọkan ti a ko tii ṣe iwadii rẹ lẹyin iṣiro.

Son Yonghee to jẹ ọkan lara awọn to n ṣiṣẹ imọtoto ni South Korea sọ pe oun ko mọ pe awọn to ni arun irẹwẹsi ọkan pọ gidi gan an lorilẹede naa.

Ọkunrin kan ọmọ orilẹede South Korea ni kiko idọti jẹ bii oogun fun aisan irẹsi ọkan foun.