You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Idasilẹ igbimọ Sharia le da alaafia ilẹ Yoruba ru
Ki lo ri to fi sọ bẹẹ?
Emi kọ o, Aarẹ Onakakanfo ilẹ Yoruba, Iba Gani Adams lo ma sọ bẹẹ ẹ
Iba Gani Adams ni atunto ijọba lo le mu idagbasoke ati alaafia jọba
Iyoku iroyin naa wa lori ikanni BBC Yoruba
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Irọ nla n'iroyin kan to sọ pe ọkọ to tẹ le Aya Aarẹ Naijiria, Sẹnẹtọ Oluremi Tinubu, lo ṣeku pa ọmọdebinrin kan lasiko abewo si ipinlẹ Ondo
Ileeṣẹ ọlọpaa ni iwadii ti fi han pe awakọ kan ti ko Bikita lo gba ọmọ naa to si ku
Alaye wa lori BBC.Com/Yoruba
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Ọkan lara awọn akẹkọọ fasiti to fara gbọta nibi iṣẹlẹ ijinigbe
To waye lọna marosẹ Ore si Benin ni a gbọ pe o wa lẹsẹ kan aye ẹsẹ kan bayii nile iwosan
ẹwẹ, awon ajinigbe ọhun ti n beere miliọnu mẹẹdogun owo itusilẹ fawọn akẹkọọ mẹwaa ti wọn gbe lọ
Awọn akẹkọọ ijọ Seventh Day Adventist naa bọ sọwọ awọn ajinigbe lọna irinajo wọn fun ipade Ajinde nipinlẹ Ogun
Fun ẹkunrẹrẹ….