Toyin Abraham náà dánrawò lórí èdè Yorùbá ní BBC
Toyin Abraham náà dánrawò lórí èdè Yorùbá ní BBC

Èèkan oṣere ni Toyin Abraham ti ọpọ tun maa n pe ni ‘Mummy Ire’
Ni aipẹ yii ni BBC Yoruba rinna ṣe pẹki rẹ.
A bere awọn ibeere to ni ṣe pẹlu ede Yoruba lọwọ rẹ, gẹgẹbi ẹni to n gbe aṣa ati ede Yoruba ga ninu awọn sinima rẹ.
Ka ma parọ, Toyin Abraham gbiyanju pupọ. Ẹyin gan ẹ funra yin wo o ninu fọnran yii.






