Kò ṣeé mà gbọ̀ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣeé mà gbọ̀ọ́
Kò ṣeé mà gbọ̀ọ́

Ajọ JAMB ti gba pe aṣiṣe oun ni ọpọ akẹkọọ to fidi rẹmi ninu idanwo UTME ọdun yii

Ọga agba JAMB, Ishiaq Oloyede, kede pe aṣiṣẹ naa waye nibudo idanwo mẹtadinlọgọjọ nipinlẹ Eko ati Imo.

Ibudo marundinladọrin lo ni o kan ni ẹkun Eko ati Oyo.

Akẹkọọ to din diẹ lẹgbẹrun mẹrin (379,997)ni JAMB ni yoo tun idanwo naa ṣe, bẹrẹ lati ọla ọjọ Ẹti.

Kan si BBC.COM/Yoruba fun ẹkunrẹrẹ.

Lllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllll;;

Jọọ, ki lo gbọ nipa irẹsi oloro ti wọn lo n pa awọn eeyan l'Eko ati Ogun?

Ọga agba Ileeṣẹ aṣọbode ilẹ wa, ẹka Seme, Ben Oramalugo, ti sọ pe ko sohun to jọ bẹẹ rara.

Oramalugo ni awọn kan lo gbe iroyin ofege to n mu ipaya wa jade.

O ni ẹnikẹni ko bẹ Ogun lọwẹ nitori irẹsi.

Hhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhhh

Wọn ti ri ọmọ Jumoke George onitiata, amọ nǹkan kò fara rọ fún-un.

Mali ni Deola ti iya rẹ n wa latọdun mẹrin sẹyin ti fohun ranṣẹ.

O ṣalaye b'aye ṣe nira nibẹ ati idi ti ko fi le wale

Fun ẹkunrẹrẹ