Kò ṣeé má gbọ̀ọ́
Ọmọogun Naijiria mẹfa lo padanu ẹmi wọn nibi ikọlu awọn agbesunmọmi Iswap laipẹ yii
Awọn agbebọn naa kọlu ibudo awọn ologun naa to wa ni ipinlẹ Borno
agbebọn mẹrinlelọgbọn pẹlu ku lasiko ikọlu naa
Gẹgẹbi alukoro ileeṣẹ ologun, Edward Buba ṣe sọ
\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\\
Mubarak Bala arakunrin kan ti ko nigbagbọ ninu Ọlọrun ti jade lẹwọn
Lẹyin ti ile ẹjọ kan nilu Kano ran lọ sẹwọn fun sisọrọ odi si Ọlọrun
Amọṣa o ni inu ewu lẹmi oun wa ati pe ọkan oun ko balẹ ki awọn kan ma baa lepa ẹmi oun
Bala ba BBC sọrọ lori idi to fi di ẹni to n tako ẹsin ati Ọlọrun
Amọṣa, gba mu o tan'ba
Kan si BBC. Com/ Yoruba fun ẹkunrẹrẹ
Llllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllllll…
Awọn agbẹ alalubọsa ni Naijiria pẹlu ti n ke irora lori ọwọngogo alubọsa to gbode bayii
Ko ye mi, ọmọ ẹlẹran a tun ṣe maa sunkun egungun ẹra?
Wọn ni gbese lawọn n jẹ labọ ọja ati pe lọwọ yii Aadojọ biliọnu naira ni gbese ọrun awọn
Ki lo wa fa a?
