Kò ṣeè má gbọ̀ọ́
Ṣé ìjọba ìpínlẹ̀ Oyo ti buwọ́lu Sharia ni?
Ki lo ri o?
Mo ri iroyin kan to ni Igbìmọ̀ Sharia ti bẹ̀rẹ̀ ìjókòó ní mọ́ṣáláṣí ńlá ìlú Oyo ni
Lati bi oṣu mẹta ni awuyewuye ti n waye lori idasilẹ ile-ẹjọ Sharia nipinlẹ Oyo
Gomina Seyi Makinde ti sọ pe ile-ẹjọ ni yoo ba awọn yanju ọrọ
,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,
'Àwọn darandaran ti lé wa kúrò l'óko, o kere tan, èèyàn méjì ni wọ́n n pa l'ọ́sẹ̀'
Nibo?
Awọn olugbe ilu Ala, nijọba ibilẹ Ariwa Akurẹ, lo ke gbajare si Gomina Aiyedatiwa bẹẹ
Awọn araalu naa sọ fun BBC pe ibẹru ti mu ki awọn sa kuro loko bayii
Ọsẹ to kọja ni awọn araalu Ala ṣe iwọde lọ si ọfiisi gomina lori ọrọ naa
Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ogun ti mu ọlọdẹ marun-un latari iku Taiwo Bolugbe toun naa jẹ ọlọdẹ.
Agbẹnusọ ọlọpaa Ogun, Omolola Odutola sọ pe lasiko ti ẹnikan lara wọn n gbiyanju lati mu ẹran ti wọn n le ninu igbo lọjọ Aiku
Ni ibọn to gbe dani jabọ, to si yin mọ oloogbe Bolugbe
