Mo kọ́ bí igi ṣe ń sọ̀rọ̀ -Arole, agbẹ́gilére
Mo kọ́ bí igi ṣe ń sọ̀rọ̀ -Arole, agbẹ́gilére

Oscar Hassan Idris Adekunle Ajasa Arole jẹ agbẹgilere nilu Abẹokuta.
Arole ni oun ko ba iṣẹ ọna nile gẹgẹ bi ọpọ oniṣẹ ọna, oun kọ ọ ni.
O ni oun tun ni iwe ẹri imọ nipa iṣẹ ọna ati gbigbẹ igi lere lati ile ẹkọṣẹ olukọni FCE Oṣiẹlẹ.

Lara igi to ni awọn maa fi n gbẹ igi lere ni igi apa, igi Iroko, igi Ọmọ, dongoyaro ati bẹẹbẹẹ lọ.
O ni oun kọ bi igi ṣe n sọrọ.
Alaye yoku n bẹ ninu fidio yii.



