Kò ṣeé má gbọ̀ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Ko see ma gboo
Kò ṣeé má gbọ̀ọ́

Ṣe o mọ pe o le fi ẹwon jura bi o ba n taja loju popo l'Eko?

Ọlọja mẹrinlelogbọn lo ti dero rimandi fun tita ọja loju popo nilu Eko

Ajọ KAI ati LAWMA to mu wọn sọ pe

Wọn kọ ibugbe to lodi sofin sibẹ.

Awọn ọmọ ganfe si n gbabẹ ṣiṣẹ ibi.

Lati mọ ohun gan ti ofin yii sọ

Kan si BBC .COM/Yoruba

///////////////////////////////////////

...........................................................................................

Àṣìrí ikú tó pa Albert Ojwang, afurasí ọmọ Kenya tó kú sí àhámọ́ ọlọ́pàá ti tú o.

Awọn akọṣẹmọṣẹ to yẹ oku rẹ wo sọ pe

Ọgbẹ ori, ifunnilọrun atawọn ọgbẹ mii wa lara ohun to fa iku rẹ.

Eyi tako ohun tawọn ọlọpaa sọ pe o la ori mọ ogiri ni

Ẹ kan soju opo BBC Yoruba fun ẹkunrẹrẹ ohun toloogbe naa ṣe gan

''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''

Ọpọ ti dero atimọle nibi iwọde to n waye Los Angeles l'Amẹrika.

Lẹyin aṣẹ Aarẹ Trump pe kawọn aṣọbode maa mu awọn ti ko ni iwe igbelu.

Ọkọ ati ile ijọba lo ti faragba lagbegbe Westlake ati Paramount to ti milẹ julọ.

Fun ẹkunrẹrẹ