Kò ṣeè má gbọ̀ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣéé mà gbọ̀ọ́
Kò ṣeè má gbọ̀ọ́

Hílàhílo ìjà ẹgbẹ́ òkùnkùn gbòde nílùú Owo, èèyàn mẹ́rín kú, ìjọba kéde ìséde lọjọ Aje

Iroyin sọ pe Olori awọn ọdọ tẹlẹ fun APC l'Ondo, Fisayo Oladipupo tawọn kan yinbọn pa lo fa wahala.

Bawo lọrọ ṣe wa tun di ti ija agba awọn ẹgbẹ okunkun tawọn mi-in tun ku?

LLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLLL

Chai, iwà àjẹbánu rápálá wọ àjọ EFCC, awọn òṣìṣẹ́ wọn kan gba ìwé ìdádúró lẹ́nu iṣẹ́

Haa, ajọ to n gbogun ti iwa ajẹbanu ni Naijiria kọ niyẹn ni?

Awọn ni o.

Atẹjade ti olori ẹka ipolongo wọn, Dele Oyewale fi sita lọjọ Aje, kede pe oṣiṣẹ mẹtadinlọgbọn niṣẹ bọ lọwọ wọn nitori aṣemaṣe ni 2024.

Iru aṣemaṣe wo ni wọn ṣe gan-an?

Kan si BBC.Com /Yoruba.

jjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjjj

''Ẹkun ojoojumọ ni mo n sun ni ireti iku fọdun mẹrinla'

Segun Olowookere, okunrin ti wọn dajọ iku fun nitori adiẹ ti wọn lo ji l'Osun lo ṣalaye bẹẹ fun BBC Yoruba.

Ba mi ka lọ loju opo wa, ko o gbọ bi Segun ṣe funra ẹ ṣalaye iriri ẹwọn lẹyin idajọ iku.