Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Ẹ gba wa o!

Ki lo de e?

Awọn akẹkọọ fasiti ipinlẹ Kwara, KWASU, lo ke gbajare lori bawọn agbebọn ṣe n ja won lole, ti wọn si n fipa ba tọkunrin-tobinrin lopọ

Laipẹ yii ni iroyin kan gba ori ayelujara lori bawọn afurasi ọdaran naa ṣe n sọsẹ lagbegbe tawọn akẹkọọ n gbe

BBC Yoruba sabẹwo si ile-ẹkọ naa lọjọ Aje

Ẹ kan soju opo wa fun abọ iwadii ti a ṣe

''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''

Ogun o ri bii iyan, ogun o ri bi ẹkọ, ẹ jogun o mi

Aarẹ orilẹede America, Donald Trump, lo kede pe

Israel ati Iran ti gba lati jẹ ki ogun o sinmi laarin wọn

Laarọ oni ọjọ Isẹgun ni Trump ṣe ikede eyi

to si kilọ fun orilẹede mejeeji pe wọn o gbọdọ tapa si adehun naa

''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''

Kinni itumọ idanwọ ti ajọ JAMB kede pe awọn akẹkọọ kan yoo tun ṣe lopin ọsẹ yii?

Bẹẹ la a bi ni, ''mop-up'' ni wọn pe orukọ idanwo ọhun lede oyinbo

Ṣebi igba meji lawọn akẹkọọ ti ṣe idanwo UTME lọdun yii tẹlẹ, ewo wa tun ni ''mop-up''?

Ti o ba fẹ mọ itumọ idanwo yii... ẹ kan si wa...