Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àjọ ajafẹtọọ ọmọniyan Amnesty International ti rọ ìjọba Nàìjíríà

láti ṣèwádìí àdó olóró iléeṣẹ́ ológun to ṣekúpa ogún èèyàn ní ìlú Maraya àti Wabi nipinlẹ Zamfara

Àwọn aráàlú náà sọ fun BBC pe

Awọn fijilante to n koju ija sawọn agbebọn to ṣekọlu siluu naa lawọn ọmọ ogun ju àdó olori

Ti wọn si ro pe awọn agbebọn lawọn koju ija si

xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx

Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Osun ti bẹrẹ iwadii

lori iṣẹlẹ ikọlu awọn ẹlẹgbẹ okunkun to waye lasiko ọdun egungun niluu Osogbo nibi ti eeyan kan ti padanu ẹmi rẹ.

Agbẹnusọ ileeṣẹ ọlọpaa Osun, Abiodun Ojelabi ṣalaye fun BBC Yoruba pe

Awọn ẹlẹẹgbẹ okunkun meji lo tẹle Egungun ti ija si bẹ silẹ laarin wọn

Ẹnikan ti iṣẹlẹ naa ṣoju rẹ sọ pe ọpọ eeyan lo farapa nibi ikọlu ọhun

xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx

Laaarin iṣẹju meje ni alaboyun n padanu ẹmi wọn lasiko ibimọ ni Naijiria

Iyẹn lagbara o!

Abọ iwadii UN gbe jade lori iku awọn iyalọmọ sọ pe Naijiria lo wa loke tente awọn orilẹ ede to buru julọ lati bimọ

Fun ẹkunrẹrẹ

Obìnrin tó ń sọ̀rọ̀ sí èèyàn létí