Tábìlì àmì ẹ̀yẹ fún ìdíje èré ìdárayá Paris Olympics fọ́dún 2024

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Ta lo n gba ami goolu to pọ julọ? Elere idaraya lati orilẹede to le ni igba lo n figa gbaga fun ami ẹyẹ ojilelọọdunrun o din ẹyọ kan ninu oniruuru ere idaraya mejilelọgbọn ti wọn n kopa ninu rẹ nibi idije ere idaraya Olympics to n waye nilu Paris. Awọn ami ẹyẹ akọkọ ni wọn yoo fun awọn elere idaraya to yege lọjọ kẹtadinlọgbọn osu keje ọdun 2024.

Akiyesi: Awọn ami ẹyẹ ti elere idaraya aladani kọọkan ba gba ko si ninu tabili yii.