Tábìlì àmì ẹ̀yẹ fún ìdíje èré ìdárayá Paris Olympics fọ́dún 2024 24 Agẹmo 2024
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1
Ta lo n gba ami goolu to pọ julọ? Elere idaraya lati orilẹede to le ni igba lo n figa gbaga fun ami ẹyẹ ojilelọọdunrun o din ẹyọ kan ninu oniruuru ere idaraya mejilelọgbọn ti wọn n kopa ninu rẹ nibi idije ere idaraya Olympics to n waye nilu Paris. Awọn ami ẹyẹ akọkọ ni wọn yoo fun awọn elere idaraya to yege lọjọ kẹtadinlọgbọn osu keje ọdun 2024.
Bi ikọ kan ti se daadaa si Ikọ Wura Fadaka Idẹ Aropọ lapapọ 1 Orilẹede Amẹrika 40 44 42 126 2 Orilẹede China 40 27 24 91 3 Orilẹede Japan 20 12 13 45 4 Ilẹ Australia 18 19 16 53 5 Orilẹede France 16 26 22 64 6 Orilẹede Netherlands 15 7 12 34 7 Ilẹ Gẹẹsi 14 22 29 65 8 Orilẹede South Korea 13 9 10 32 9 Orilẹede Italy 12 13 15 40 10 Orilẹede Germany 12 13 8 33 11 Orilẹede New Zealand 10 7 3 20 12 Orilẹede Canada 9 7 11 27 13 Orilẹede Uzbekistan 8 2 3 13 14 Orilẹede Hungary 6 7 6 19 15 Orilẹede Spain 5 4 9 18 16 Orilẹede Sweden 4 4 3 11 17 Orilẹede Kenya 4 2 5 11 18 Orilẹede Norway 4 1 3 8 19 Orilẹede Ireland 4 - 3 7 20 Ilu Brasil 3 7 10 20 21 Orilẹede Iran 3 6 3 12 22 Orilẹede Ukraine 3 5 4 12 23 Orilẹede Romania 3 4 2 9 24 Orilẹede Georgia 3 3 1 7 25 Orilẹede Belgium 3 1 6 10 26 Orilẹede Bugaria 3 1 3 7 27 Orilẹede Serbia 3 1 1 5 28 Orilẹede Chech 3 - 2 5 29 Orilẹede Denmark 2 2 5 9 30 Orilẹede Azerbaijan 2 2 3 7 30 Orilẹede Croatia 2 2 3 7 32 Orilẹede Cuba 2 1 6 9 33 Orilẹede Bahrain 2 1 1 4 34 Orilẹede Slovenia 2 1 - 3 35 Orilẹede Taiwan 2 - 5 7 36 Orilẹede Austria 2 - 3 5 37 Orilẹede Hong Kong 2 - 2 4 37 Orilẹede Phillippines 2 - 2 4 39 Orilẹede Algeria 2 - 1 3 39 Orilẹede Indonesia 2 - 1 3 41 Orilẹede Israel 1 5 1 7 42 Orilẹede Poland 1 4 5 10 43 Orilẹede Kazakhstan 1 3 3 7 44 Orilẹede Jamaica 1 3 2 6 44 Orilẹede South Africa 1 3 2 6 44 Orilẹede Thailand 1 3 2 6 47 Orilẹede Ethiopia 1 3 - 4 48 Orilẹede Switzerland 1 2 5 8 49 Orilẹede Ecuador 1 2 2 5 50 Orilẹede Portugal 1 2 1 4 51 Orilẹede Greece 1 1 6 8 52 Orilẹede Argentina 1 1 1 3 52 Orilẹede Egypt 1 1 1 3 52 Orilẹede Tunisia 1 1 1 3 55 Orilẹ́ẹede Boswana 1 1 - 2 55 Orilẹede Chile 1 1 - 2 55 Erekusu Saint Lucia 1 1 - 2 55 Orilẹede Uganda 1 1 - 2 59 Orilẹede Dominican Republic 1 - 2 3 60 Orilẹede Guatemala 1 - 1 2 60 Orilẹede Morrocco 1 - 1 2 62 Orilẹede Dominican 1 - - 1 62 Orilẹede Pakistan 1 - - 1 64 Orilẹede Turkey - 3 5 8 65 Orilẹede Mexico - 3 2 5 66 Orilẹede Armenia - 3 1 4 66 Orilẹede Colombia - 3 1 4 68 Orilẹede Kyrgyzstan - 2 4 6 68 Orilẹede North Korea - 2 4 6 70 Orilẹede Lithuania - 2 2 4 71 Orilẹede India - 1 5 6 72 Orilẹede Moldova - 1 3 4 73 Orilẹede Kosovo - 1 1 2 74 Orilẹede Cyprus - 1 - 1 74 Orilẹede Fiji - 1 - 1 74 Orilẹede Jordan - 1 - 1 74 Orilẹede Mongolia - 1 - 1 74 Orilẹede Panama - 1 - 1 79 Orilẹede ajikistan - - 3 3 80 Orilẹede Albania - - 2 2 80 Orilẹede Grenada - - 2 2 80 Orilẹede Malaysia - - 2 2 80 Orilẹede Puerto Rico - - 2 2 84 Orilẹede Cote d‘ivoire - - 1 1 84 Erekusu Cape Verde - - 1 1 84 Orilẹede Peru - - 1 1 84 Orilẹede Quatar - - 1 1 84 Orilẹede Singapore - - 1 1 84 Orilẹede Slovakia - - 1 1 84 Orilẹede Zambia - - 1 1
Akiyesi: Awọn ami ẹyẹ ti elere idaraya aladani kọọkan ba gba ko si ninu tabili yii.