Wo pàtàkì ọmú fún ọmọ ìkókó láàárín ọjọ́ mẹ́ta àkọ̀kọ̀ lẹ́yìn tí wọ́n bíi

Àkọlé fídíò, Wo pàtàkì ọmú fún ọmọ ìkókó láàárín ọjọ́ mẹ́ta àkọ̀kọ̀ lẹ́yìn tí wọ́n bíi
Wo pàtàkì ọmú fún ọmọ ìkókó láàárín ọjọ́ mẹ́ta àkọ̀kọ̀ lẹ́yìn tí wọ́n bíi

Lọsẹ yii, lori ẹto laa-han mi ko ye lori awọn ọr to nii ṣe pẹlu awọn obinrin, pataki ọmu mimu la n gbe yẹwo.

Agbeyẹwo way ii w ani ibamu pẹlu alaye ti ajọ ilera awọn ọmọde lagbaye, Unicef gbe sita ti wọn si n fọnrere rẹ kaakiri agbaye pe ọmu mimu ṣe pataki pupọ lati wakati akọkọ ti a ba ti bi ọmọ tuntun.

Wọn ni o n ṣe ọpọlọpọ iṣẹ lati mojuto ooru ara ọmọ ikoko.

Bakan naa ni wọn tun ṣalaye pe iwadi ti fihan pe lasiko ti ọmọ ikoko n gbẹnu si ọmu iya rẹ yii, o n lanfani lati fara ko awọn Kokoro kan to dara fun un lati awọ ara iya rẹ.

Awọn kokoro aifojuri wọnyii ni wọn maa n daabo bo ọmọ ikoko lọwọ awọn arun alakoran ti yoo si tun mu ki awọn alumọni ara to n daabobo ara lọwọ awọn aisan o tubọ lagbara ati okun sii.