Ọlọ́run, jọ̀wọ́ má jẹ́ kí n rí ohun tí yóò mú mi fi igbó mímu sílẹ̀ - Naira Marley

Aworan Azeez Fashola

Oríṣun àwòrán, Instagram

Gbajugbaja olorin takasufe, Azeez Fashola ti ọpọ mọ si Naira Marley ni o ra wọ ẹbẹ si ẹlẹda rẹ pe ko maa jẹ ki oun ri ohun ti yoo mu oun jawọ ninu igbo mimu.

Naira Marley lo gbe ọrọ naa jade lori opo ayelujara rẹ Twitter, ti awọn ololufẹ rẹ si ni awọn ko ni baa ṣe amin si adura naa.

Ọpọ igba ni Naira Marley ti dero ileẹjọ nitori ẹsun kan tabi omiran.

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: The BBC is not responsible for the content of external sites.

End of X post, 1

Ọpọ awọn ololufẹ rẹ lo ti tu lọ soju opo olorin naa lati pe akiyesi rẹ si ewu to wa ninu siga tabi igbo minu, ti wọn si ni awọn ko ni baa ṣe amin adura naa.

Bi awọn kan ṣe n bu u pe o gbe irufẹ ọrọ naa jade ni awọn miiran n kan sara si i lori igbesẹ naa ti wọn si baa ṣe amin adura.

@NwaEzeke ni "Ko yẹ ko gbe iru nkan bayii jade sori ayelujara, awokọṣe lo jẹ fun awọn ọdọ ṣugbọn eyi to gbe jade ni ko dara rara."

@Vikynaz02 ni "Sugbọn kilode ti o ko le jawọ ninu igbo mimu, o lero pe ara rẹ pe ṣugbọn ọjọ n lọ lori rẹ."

@oficiallyneto ni "Emi ko ni ba ẹ se amin si adura eleyi."

Skip X post, 2
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: The BBC is not responsible for the content of external sites.

End of X post, 2

Skip X post, 3

End of X post, 3

Skip X post, 4

End of X post, 4

Skip X post, 5

End of X post, 5