Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

[13:44, 01/05/2025] Joshua Adetunji: Ọwọngogo to gbode ko jẹ kowo oṣu to o na mọ!

Ọ gbẹnu tan o, ẹka apapọ ẹgbẹ oṣiṣẹ lawọn ipinlẹ ni Naijiria ti beere fun ẹkunwo owo oṣu

Bi wọn ṣe n ṣayajọ ọjọ oṣiṣẹ lonii

Wọn kepe ijọba lati wa ojutuu s'ọwọngogo ounjẹ, ilegbee atawọn nkan mi to ti gbowo lori

Ẹkunrẹrẹ wa loju ikanni BBC Yoruba

''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''

Agbẹdọ!

Ileẹjọ giga kan niluu Ibadan ti paṣẹ pe Imaamu Agba Ogbomoso, Alhaji Shekh Toliat Ayilara

ko le fi Sẹnẹtọ Hamzat Adeseun ati Shaykh Idris Ibrahim Alao jẹ oye musulumi niluu Ogbomoso

Ki wa nidi tile ẹjọ sọ bẹẹ?

Alaye wa loju opo BBC.Com/Yoruba

''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''

Njẹ o mọ pe o ṣee ṣe ki gbajumọ olorin takafufee Portable ma faṣọ penpe roko ọba, bo tilẹ jẹ pe adajọ ti ju u sẹwọn oṣu mẹta

Ẹnh ẹnh, kinni idi abajọ?

Adajọ majisireeti ni Portable le san faini ẹgbẹrun lọna ọgbọn naira ti ko ba fẹ ṣẹwọn

Ileẹjọ fidi rẹ mulẹ pe ọmọ Olalomi jẹbi ẹsun lilu arakunrin kan lalubami ati jiji ohun elo orin ti wọn fi kan an