Kò ṣeé má gbọ̀ọ́
Rogbodiayan to n lọ lẹgbẹ oṣelu PDP maa tun ti gbọna mii yọ
Ki lo tun ṣẹlẹ?
Minisita olu ilu orilẹede Naijiria, Abuja, Nyesom Wike, lo ma fẹsun kan Gomina Seyi Makinde ipinlẹ Oyo
Wi pe kinni?
O ni Makinde lo n fa ọpọ wahala to n ṣẹlẹ lẹgbẹ oṣelu naa
nitori bo ṣe kuna lati ko ipa tirẹ lori adehun ti wọn jọ fẹnuko le lori
Kinni Makinde wa sọ?
Kan soju opo BBC Yoruba ti o ba fẹ mọ
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Báwo ni èsì àtúnṣe ìdánwò UTME tí JAMB ṣẹ̀ṣẹ̀ gbé jáde ṣe rí gan an?
O ma gbe pẹẹli si ju eyi ti wọn fi sita tẹlẹ lọ
Akẹkọọ meloo lo ṣe daadaa ninu esi idanwo ọhun?
Lọ sori ikanni BBC Yoruba fun atupalẹ esi idanwo naa
'''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Awọn alaṣẹ orilẹede Saudi Arabia ti fofin de gbajugbaja onimọ nipa ẹsin musulumi, Sheikh Ahmad Gumi
Wi pe ko gbọdọ wa si orilẹede naa fun ise iṣẹ Hajj ọdun yii
Ki ni wọn lo se?
Fun ẹkunrẹrẹ iroyin yii…

