Wo àwòrán bí àwọn Kristẹni ṣe ṣe àyájọ́ ọjọ́ Ẹtì rere

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

Ọjọ Ẹti rere ni ọjọ Ẹti saaju ọjọ ajinde .

Ọdọọdun ni ayajọ yii ma n waye lati fi ṣe iranti Jesu Kristi, paapa ijinde Jesu Kristi.

Saaju, awọn Kristẹni ma n ṣe ayajọ Ọjọ Ẹti rere pẹlu ibanujẹ ọkan, ti wọn si ma n fi ọjọ naa gba awẹ.

Ni ọdun 2025 yii, Ọjọ Ẹti ree bọ si ọjọ Kejidinlogun oṣu kẹrin.

Ẹ fun oju yii lounjẹ pẹlu awọn aworan ayajọ Ọjọ Ẹti kaakiri agbaye ni ọdun 2025.